MENU

Where the world comes to study the Bible

Awon Igbese Merin Sodo Olorun

1. Olorun Feran Re!

Bibeli so wipe, ‘ Nitori Olorun fe araiye tobee ge ti o fi Omo bibi re kansoso funni, ki enikeni ti o ba gba a gbo ma ba segbe, sugbon ki o le ni iye ainipekun”


Isoro ibe ni wipe

2. Gbogbo wa ni o ti se, so tabi ro awon ohun ti o lodi. Eyi ni a npe ni ese, ese wa si ti yawaipa kuro lado Olorun. (

Bibeli so wipe “Gbogbo enia li o sa ti se, ti won si ti kuna ogo Olorun”.Olorun pe, o si je mimo, ati wipe ese wa ya wa kuro lodo Olorun titi lae. Bibeli so wipe “iku ni ere ese.”

Irihin rere ni wipe, ni nkan bi egberun odun meji sehin,

3. Olorun ran Omo Re nikan soso lati ku fun ese wa.

Jesu ni Omo Olorun. O gbe igbe aye alailese o si ku lori agbelebu lati san gbese fun ese wa. “ Sugbon Olorun fi ife On papa si wa han ni eyi pe, nigbati awa je elese, Kristi ku fun wa.”

Jesu ji dide kuro ninu oku osi ngbe orun pelu Olorun Baba Re. O fi ebun iye aiyeraye han funwa—ati pelu wipe ki a le gbe papo pelu Re ni Orun bi a ba lee gbaagbo gegebi Oluwa ati Olugbala wa. Jesu wi fun u pe “Emi li ona, ati otito, ati iye: ko si enikeni ti o le wa sodo Baba, bikose nipase mi.”

Olorun na owo ife si o, O si nfe ki je omo Re. “ Sugbon iye awon ti o gba a awon li ofi agbara fun lati di Omo Olorun, ani awon na ti o gba oruko re gbo.” Iwo na le yan lati bere idariji lowo jesu Kristi fun idariji ese re ki o si wo inu aye re lo gegebi oluwa ati Olugbala re.


4. Bi o ba fe gba Kristi o lee so Fun u ki O je Olugbala ati Oluwa bi o ti gba adura bayi…

”Jesu Oluwa, mo gbagbo wipe omo Olorun ni iwo nse.Mo dupe fun iku re lori agbelebu tori awon ese mi. Jowo dari awon ese mi ji mi ki o si fun mi ni iye ainipekun.Mo gba adura wipe ki o wo inu aye mi ati okan mi gegebi Oluwa ati olugbala mi. Mo fe maa sin o ni gbogbo igba.”


Nje o gba adurayi?

Related Topics: Soteriology (Salvation), Evangelism

Report Inappropriate Ad